Yorùbá-English Translation.

Akorede Adetunji

Personal Trainer
Translator
Mo tín fé lati ma bá àwon òpòlópò èyàn kó ède Yorùbá sùgbón mi o rí ònà lati gbà se. Mo wá pàdé ààyè ayélújára contra.com tí molè ma ran àwon èyàn náà lówó ní tí ède Yorùbá. Inú mi síì dùn pé mo ti ri ònà náà tí mo le fi kó àti fi mò. 🙂
I've been wanting to help many people learn Yorùbá language but I couldn't find a way to do so. I then met the contra.com website where I can help others in terms of Yorùbá language. I am very glad to find a way to teach and to learn. 🙂
Partner With Akorede
View Services

More Projects by Akorede